Ìṣe Àwọn Aposteli 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

àfi pé láti ìlú dé ìlú ni Ẹ̀mí Mímọ́ ń fi àmì hàn mí pé ẹ̀wọ̀n ati ìyà ń dúró dè mí níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:18-24