Ìṣe Àwọn Aposteli 20:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń tẹnu mọ́ ọn fún àwọn Juu ati àwọn Giriki pé kí wọn yipada sí Ọlọrun, kí wọn ní igbagbọ ninu Oluwa Jesu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:11-23