Ìṣe Àwọn Aposteli 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ mọ̀ bí mo ti lo gbogbo àkókò mi láàrin yín láti ìgbà tí mo ti kọ́kọ́ dé ilẹ̀ Esia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:9-19