Ìṣe Àwọn Aposteli 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Paulu ti pinnu láti wọkọ̀ kọjá Efesu, kí ó má baà pẹ́ pupọ ní Esia, nítorí ó ń dàníyàn pé bí ó bá ṣeéṣe, òun fẹ́ ṣe Àjọ̀dún Pẹntikọsti ní Jerusalẹmu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:8-22