Ìṣe Àwọn Aposteli 20:13 BIBELI MIMỌ (BM)

A bọ́ siwaju, a wọkọ̀ ojú omi lọ sí Asọsi. Níbẹ̀ ni a lérò pé Paulu yóo ti wá bá wa tí òun náà yóo sì wọkọ̀. Òun ló ṣe ètò bẹ́ẹ̀ nítorí ó fẹ́ fẹsẹ̀ rìn dé ibẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:7-18