Ìṣe Àwọn Aposteli 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Dafidi kò gòkè lọ sí ọ̀run. Ohun tí Dafidi sọ ni pé,‘Oluwa wí fún oluwa mi pé:Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:24-35