Ìṣe Àwọn Aposteli 19:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n mọ̀ pé Juu ni, wọ́n figbe ta, wọ́n ń pariwo fún ìwọ̀n wakati meji. Wọ́n ń kígbe pé, “Oriṣa ńlá ni Atẹmisi, oriṣa àwọn ará Efesu!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:26-39