Ìṣe Àwọn Aposteli 19:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́, inú bí wọn pupọ. Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí kígbe, wọ́n ń wí pé, “Oriṣa ńlá ni Atẹmisi, oriṣa àwọn ará Efesu!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:19-31