Ìṣe Àwọn Aposteli 19:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà tí ń jẹ́ Demeteriu, alágbẹ̀dẹ fadaka. A máa fi fadaka ṣe ilé ìsìn ti oriṣa Atẹmisi; èyí a sì máa mú èrè pupọ wá fún àwọn tí ń ṣe iṣẹ́ ọnà yìí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:15-27