Ìṣe Àwọn Aposteli 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá rán àwọn meji ninu àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀, Timoti ati Erastu, lọ sí Masedonia ṣugbọn òun alára dúró fún ìgbà díẹ̀ sí i ní Esia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:12-23