Ìṣe Àwọn Aposteli 19:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Báyìí ni ọ̀rọ̀ Oluwa fi agbára hàn; ó ń tàn kálẹ̀, ó sì ń lágbára.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:19-28