Ìṣe Àwọn Aposteli 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Sila ati Timoti dé láti Masedonia, Paulu wá fi gbogbo àkókò rẹ̀ sílẹ̀ fún iwaasu, ó ń tẹnu mọ́ ọn fún àwọn Juu pé Jesu ni Mesaya.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:1-10