Ìṣe Àwọn Aposteli 18:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé iṣẹ́ kan náà ni wọ́n ń ṣe, Paulu lọ wọ̀ lọ́dọ̀ wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́. Iṣẹ́ ọnà awọ tí wọ́n fi ń ṣe àgọ́ ni wọ́n ń ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:1-13