Ìṣe Àwọn Aposteli 18:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá bá àwọn Juu jiyàn níwájú gbogbo àwùjọ, a máa borí wọn, kedere ni ó ń fihàn láti inú Ìwé Mímọ́ pé Jesu ni Mesaya.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:24-28