Ìṣe Àwọn Aposteli 18:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni gbogbo wọ́n bá mú Sositene, olórí ilé ìpàdé àwọn Juu, wọ́n ń lù ú níwájú kóòtù. Ṣugbọn Galio kò pé òun rí wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:15-19