Ìṣe Àwọn Aposteli 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn tí ó bá jẹ́ àríyànjiyàn nípa àwọn ọ̀rọ̀ tabi orúkọ, tabi òfin yín, ẹ lọ rí sí i fúnra yín. N kò fẹ́ dá irú ẹjọ́ bẹ́ẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:12-24