Ìṣe Àwọn Aposteli 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Galio di gomina Akaya, àwọn Juu fi ohùn ṣọ̀kan láti dìde sí Paulu. Wọ́n bá mú un lọ sí kóòtù níwájú Galio.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:3-14