Ìṣe Àwọn Aposteli 17:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan ninu wọn gbàgbọ́, wọ́n fara mọ́ Paulu ati Sila. Ọ̀pọ̀ ninu wọn jẹ́ Giriki, wọ́n ń sin Ọlọrun; pupọ ninu àwọn obinrin sì jẹ́ eniyan pataki-pataki.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1-8