Ìṣe Àwọn Aposteli 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Paulu ń dúró dè wọ́n ní Atẹni, ó rí ìlú náà bí ó ti kún fún ère oriṣa. Eléyìí sì dùn ún dọ́kàn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:9-23