Ìṣe Àwọn Aposteli 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yìí ṣe onínú rere ju àwọn Juu ti Tẹsalonika lọ. Wọ́n fi ìtara gbọ́ ọ̀rọ̀ náà. Lojoojumọ ni wọ́n ń wá inú Ìwé Mímọ́ wò láti rí bí àwọn ohun tí wọ́n kọ́ wọn rí bẹ́ẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1-21