Ìṣe Àwọn Aposteli 16:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń lọ láti ìlú dé ìlú, wọ́n ń sọ fún wọn nípa ìpinnu tí àwọn aposteli ati àwọn àgbààgbà ní Jerusalẹmu ṣe, wọ́n sì ń gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n pa wọ́n mọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:1-7