Ìṣe Àwọn Aposteli 16:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó ń ṣọ́ ilé ẹ̀wọ̀n náà bá lọ jíṣẹ́ fún Paulu pé, “Àwọn adájọ́ ti ranṣẹ pé kí á da yín sílẹ̀. Ẹ jáde kí ẹ máa lọ ní alaafia.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:35-40