Ìṣe Àwọn Aposteli 16:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá mú wọn wọ ilé, ó fún wọn ní oúnjẹ. Inú òun ati gbogbo ìdílé rẹ̀ dùn pupọ nítorí ó ti gba Ọlọrun gbọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:32-40