Ìṣe Àwọn Aposteli 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń tẹ̀lé Paulu ati àwa náà, ó ń kígbe pé, “Àwọn ọkunrin yìí ni iranṣẹ Ọlọrun Ọ̀gá Ògo; àwọn ni wọ́n ń waasu ọ̀nà ìgbàlà fun yín.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:11-19