Ìṣe Àwọn Aposteli 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin kan wà níbẹ̀ tí ó ń jẹ́ Lidia, ará Tiatira, tí ó ń ta aṣọ àlàárì. Ó jẹ́ ẹnìkan tí ó ń sin Ọlọrun. Ó fetí sílẹ̀, Ọlọrun ṣí i lọ́kàn láti gba ohun tí Paulu ń sọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:7-24