Ìṣe Àwọn Aposteli 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbàrà tí ó rí ìran náà, a wá ọ̀nà láti lọ sí Masedonia; a pinnu pé Ọlọrun ni ó pè wá láti lọ waasu fún wọn níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:9-18