Ìṣe Àwọn Aposteli 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò fi ìyàtọ̀ kankan sáàrin àwa ati àwọn; ó wẹ ọkàn wọn mọ́ nítorí wọ́n gba Jesu gbọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:2-12