Ìṣe Àwọn Aposteli 15:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Paulu kò rò pé ó yẹ láti mú un lọ, nítorí ó pada lẹ́yìn wọn ní Pamfilia, kò bá wọn lọ títí dé òpin iṣẹ́ náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:36-41