Ìṣe Àwọn Aposteli 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà a rán Juda ati Sila, láti fẹnu sọ ohun kan náà tí a kọ sinu ìwé fun yín.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:20-34