Ìṣe Àwọn Aposteli 15:25 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti wá pinnu, gbogbo wa sì fohùn sí i, a wá yan àwọn eniyan láti rán si yín pẹlu Banaba ati Paulu, àwọn àyànfẹ́ wa,

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:20-35