Ìṣe Àwọn Aposteli 15:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi ìwé rán wọn, pé:“Àwa aposteli ati àwa alàgbà kí ẹ̀yin tí kì í ṣe Juu ní Antioku, Siria ati Silisia; a kí yín bí arakunrin sí arakunrin.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:18-28