Ìṣe Àwọn Aposteli 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó di ọ̀rọ̀ líle ati àríyànjiyàn ńlá láàrin àwọn ati Paulu ati Banaba. Ni ìjọ bá pinnu pé kí Paulu ati Banaba ati àwọn mìíràn láàrin wọn lọ sọ́dọ̀ àwọn aposteli ati àwọn alàgbà ní Jerusalẹmu láti yanjú ọ̀rọ̀ náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:1-9