Ìṣe Àwọn Aposteli 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Lẹ́yìn èyí, n óo tún ilé Dafidi tí ó ti wó kọ́.N óo tún ahoro rẹ̀ mọ,n óo sì gbé e ró.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:6-22