Ìṣe Àwọn Aposteli 15:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni ti ròyìn ọ̀nà tí Ọlọrun kọ́kọ́ fi ṣe ìkẹ́ àwọn tí kì í ṣe Juu kí ó lè mú ninu wọn fi ṣe eniyan tirẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:9-17