Ìṣe Àwọn Aposteli 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ńṣe ni gbogbo àwùjọ dákẹ́ jẹ́ẹ́. Wọ́n wá fetí sílẹ̀ sí ohun tí Banaba ati Paulu níí sọ nípa iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu tí Ọlọrun tọwọ́ wọn ṣe láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:7-16