Ìṣe Àwọn Aposteli 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn aposteli mọ̀, wọ́n sálọ sí Listira ati Dabe, ìlú meji ní Likaonia, ati àwọn agbègbè wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:1-10