Ìṣe Àwọn Aposteli 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyapa bẹ́ sáàrin àwọn eniyan ninu ìlú; àwọn mìíràn fara mọ́ àwọn Juu, àwọn mìíràn fara mọ́ àwọn aposteli.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:3-8