Ìṣe Àwọn Aposteli 14:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wọ ọkọ̀ ojú omi láti ibẹ̀ lọ sí Antioku ní Siria níbi tí wọ́n ti kọ́ fi wọ́n sábẹ́ ojurere Ọlọrun fún iṣẹ́ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ parí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:20-28