Ìṣe Àwọn Aposteli 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n yan àgbà ìjọ fún wọn ninu ìjọ kọ̀ọ̀kan. Nígbà tí wọ́n ti gbadura, tí wọ́n sì ti gbààwẹ̀, wọ́n fi wọ́n lé ọwọ́ Oluwa tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lé.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:18-25