Ìṣe Àwọn Aposteli 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn onigbagbọ pagbo yí i ká títí ó fi dìde tí ó sì wọ inú ìlú lọ. Ní ọjọ́ keji ó gbéra lọ sí Dabe pẹlu Banaba.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:10-28