Ìṣe Àwọn Aposteli 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òde kí á tó wọ odi ìlú ni tẹmpili Seusi wà. Baba olórìṣà Seusi bá mú mààlúù ati òdòdó jìngbìnnì, òun ati ọpọlọpọ èrò, wọ́n ń bọ̀ lẹ́nu odi ìlú níbi tí pẹpẹ Seusi wà, wọ́n fẹ́ wá bọ wọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:6-20