Ìṣe Àwọn Aposteli 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan rí ohun tí Paulu ṣe, wọ́n kígbe ní èdè Likaonia pé, “Àwọn oriṣa ti di eniyan, wọ́n tọ̀run wá sáàrin wa!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:9-13