Ìṣe Àwọn Aposteli 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé Ikoniomu, wọ́n lọ sí ilé ìpàdé àwọn Juu gẹ́gẹ́ bí ìṣe wọn. Wọ́n sọ̀rọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọpọlọpọ ninu àwọn Juu ati àwọn Giriki fi gba Jesu gbọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:1-9