Ìṣe Àwọn Aposteli 13:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn tí kì í ṣe Juu gbọ́, inú wọn dùn. Wọ́n dúpẹ́ fún ọ̀rọ̀ Oluwa. Gbogbo àwọn tí a ti yàn láti ní ìyè ainipẹkun bá gbàgbọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:42-52