Ìṣe Àwọn Aposteli 13:41 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Ẹ wò ó, ẹ̀yin ẹlẹ́gàn, kí ó yà yín lẹ́nu, kí ẹ sì parun!Nítorí n óo ṣe iṣẹ́ kan ní àkókò yín,tí ẹ kò ní gbàgbọ́ bí ẹnìkan bá ròyìn rẹ̀ fun yín.’ ”

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:38-39-51