Ìṣe Àwọn Aposteli 13:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí Dafidi ti sin ìran tirẹ̀ tán gẹ́gẹ́ bí ète Ọlọrun, ó sun oorun ikú, ó lọ bá àwọn baba rẹ̀, ara rẹ̀ rà nílẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:26-45