Ìṣe Àwọn Aposteli 13:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún ọpọlọpọ ọjọ́ ni ó fi ara hàn fún àwọn tí wọ́n bá a wá sí Jerusalẹmu láti Galili. Àwọn ni ẹlẹ́rìí fún gbogbo eniyan pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:29-34