Ìṣe Àwọn Aposteli 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà wọ́n bèèrè fún ọba; Ọlọrun bá fún wọn ní Saulu ọmọ Kiṣi, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini. Ó jọba fún ogoji ọdún.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:16-25