Ìṣe Àwọn Aposteli 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Orílẹ̀-èdè meje ni ó parẹ́ ní ilẹ̀ Kenaani nítorí tiwọn, ó sì jẹ́ kí wọ́n jogún ilẹ̀ wọn,

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:18-23