Ìṣe Àwọn Aposteli 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n la ilẹ̀ náà kọjá láti Pega títí wọ́n fi dé ìlú Antioku lẹ́bàá ilẹ̀ Pisidia. Wọ́n lọ sí ilé ìpàdé àwọn Juu ní Ọjọ́ Ìsinmi, wọ́n bá jókòó.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:4-21